[LYRICS] Brymo – Adèdótun




(Verse 1)
Awon adan fo loke, won fanka s’oju orun, won ma mobi won lo, Eledua lon s’ke won
Ko keyin sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re

(Chorus)
Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh

(Verse 2)
Awon Adan fo loke, nigba igba won kun oju orun, won ma mo oun wonje, Eledua lo n so won lo n bo won
Ko pawon sile ore oh, oun wa lo sokoto, o wa la po sokoto

(Chorus)
Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh

(Outro)
Ko pawon sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re oh

Comments

Popular Posts