[LYRICS] Brymo – Òrun n Móoru




Te ti kogbo
Ile oba ti gbana
Awon ijoye
Won ni kosowo lowo oba
Won n soro re leyin
Olori loun rofo loba n sanra

Orun n moruuuu
Orun n moruuuu
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Oba o ye
Ko pa ri
Ko binu
Oni ki won pade oun laafin
Awon ijoye
Won tiju
Won soro re leyin
Olori lo n roka
Loba n sanra

Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Comments

Popular Posts